Idajọ Irun ti a maa nki nigbati Ọsan ba di Oru (Sọlaatul-Kusuuf) cover

Podcast

Idajọ Irun ti a maa nki nigbati Ọsan ba di Oru (Sọlaatul-Kusuuf)

Sharafuddeen Gbadebọ Raji

Alaye waye ninu waasi yi nipa bi Ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- ti se ki irun bi osan ba di oru ni oju aye re pelu awon idajo irun yii. Oro si tun waye lori wipe oorun ati osupa ninu awon amin agbara Olohun ni won wa, won kii wo okunkun nitori iku eniyan kan tabi wiwa laaye re.

Episodes

0
Indexing this feed

Episodes will appear here as soon as the worker finishes.

Prefer another app? Listen on Apple Podcasts