Agboye Adadaale ninu Esin ni odo Awon ti won wa ni oju ona Sunna cover

Podcast

Agboye Adadaale ninu Esin ni odo Awon ti won wa ni oju ona Sunna

Rafiu Adisa Bello

Ibanisoro yi so ni ekunrere nipa itumo adadaale ninu esin pelu awon eri lati inu Al-kurani ati Sunna Ojise. O si se alaye ewu ti o wa nibi ki musulumi maa tele awon ti won ba n da adadaale ninu esin. Ni afikun, o tun se alaye awon majemu ti a fi maa nmo adadaale nitori awon iruju ti o wa fun awon Musulumi kan lori re.

Episodes

0
Indexing this feed

Episodes will appear here as soon as the worker finishes.

Prefer another app? Listen on Apple Podcasts